NewsBabel NewsBabel

Global headlines in real time

← Back to Direct feed

Awọn ọdọ to n ṣe iwọde pelu oniruuru akọle lọwọ

16 Sep 2026, 17:33 GMT
Download metadata bundle
BBC logo
Live

Nibi ikọlu to waye ni garaaji Mayfair naa ni wọn ti yinbọn pa ọkan lara awọn oloye ẹgbẹ oṣelu Accord nipinlẹ naa, Olalekan Oyeymi, ẹni tọpọ mọ si Emir Ajagungbade.